Kii se orisa lo n gba eje eniyan bi kose agbara okunkun to wa Lara re lo n mu eje eniyan, Sugbon eyin onisegun tabi alaafa tabi Woli alagbara okunkun, Olorun n wo yin o,
KO ye ko yawalenu lati gbo eyi, nitori gbogbo enikeni to ba nlo agbara aye yi, dandan ni ko ba esu jeun po, Nkan yi si nsele laarin gbogbo esin meteeta to won ko Le duro de Eleda won,
awon keferi elebo paraku awon Eranko muje muje yi won ti so ile yoruba di idakuda. ooo ye ki awon agbofiro sise lori awon babalawo yi
Oloriburuku ni e Lori oro to so yii
Eewọ ni kí a fi Ọmọ Ènìyàn bọ Orisa ni ilẹ̀ kóòtù ajíre.
Ayéfẹ́lẹ́ ni lati fi ojú ọkùnrin hàn fún araye.
Awon kenferi nse iwode aiye tibaje Omo ole ti bere SI ni da ajo
Hummn iro npa iro ni gbogbo e, orisa wo lo ngba eje eyan, e so fun wa e je kagbo!
Kii se orisa lo n gba eje eniyan bi kose agbara okunkun to wa Lara re lo n mu eje eniyan, Sugbon eyin onisegun tabi alaafa tabi Woli alagbara okunkun, Olorun n wo yin o,
Kini oruko Orisa re to nfi eniyan rubo ? Ejeki wo fi oju re han.
Nigba to ta ile męta to fi owo ęję ko kilowafi owo ile na şe nitori wipe koyę kofi owo na ra ikan kan rara .
Morope awon elesin abalaye ni awon ki npaniyan. Ki lo ndun won ninu asiri ki eni yi tu? Sebi won ni elesin yato si elebi😢😢.
KO ye ko yawalenu lati gbo eyi, nitori gbogbo enikeni to ba nlo agbara aye yi, dandan ni ko ba esu jeun po, Nkan yi si nsele laarin gbogbo esin meteeta to won ko Le duro de Eleda won,
😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂.....
Ibere mi se osah maun gba boli ati epa ni?
Oloriburuku ni aiyefele omo ale ogun lo pa aiyefele
You need medical help
When you no get a successful person in your family
Jealousy lo nba e ja, se Ayefele lo pa awon eniyan wonyi?
You can not see success in your life.